Daniẹli 11:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba Siria yóo ṣe wọ́n bí ó ti fẹ́ láìsí àtakò, yóo dúró ní Ilẹ̀ Dáradára náà, gbogbo rẹ̀ yóo sì wà ní ìkáwọ́ rẹ̀.

Daniẹli 11

Daniẹli 11:14-23