Daniẹli 11:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba Siria yóo wá dóti ìlú olódi kan, yóo sì gbà á. Àwọn ọmọ ogun Ijipti kò ní lágbára láti dojú ìjà kọ ọ́, àwọn akikanju wọn pàápàá kò ní lágbára mọ́ láti jagun.

Daniẹli 11

Daniẹli 11:13-20