Daniẹli 10:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi nìkan ni mo kù tí mo sì rí ìran ńlá yìí. Kò sí agbára kankan fún mi mọ́; ojú mi sì yipada, ó wá rẹ̀ mí dẹẹ.

Daniẹli 10

Daniẹli 10:1-14