Daniẹli 10:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi nìkan ni mo rí ìran yìí, àwọn tí wọ́n wà pẹlu mi kò rí i, ṣugbọn ẹ̀rù bà wọ́n, wọ́n sì sápamọ́.

Daniẹli 10

Daniẹli 10:1-10