Daniẹli 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun fún àwọn ọdọmọkunrin mẹrẹẹrin yìí ní ọgbọ́n, ìmọ̀, ati òye; Daniẹli sì ní ìmọ̀ láti túmọ̀ ìran ati àlá.

Daniẹli 1

Daniẹli 1:11-21