Daniẹli 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹni tí ń tọ́jú wọn bẹ̀rẹ̀ sí fún wọn ní ẹ̀wà, dípò oúnjẹ aládùn tí wọn ìbá máa jẹ ati ọtí tí wọn ìbá máa mu.

Daniẹli 1

Daniẹli 1:13-21