Daniẹli 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, kí o wá fi wá wé àwọn tí wọn ń jẹ lára oúnjẹ àdídùn tí ọba ń jẹ, bí o bá ti wá rí àwa iranṣẹ rẹ sí ni kí o ṣe ṣe sí wa.”

Daniẹli 1

Daniẹli 1:12-21