Daniẹli 1:12 BIBELI MIMỌ (BM)

“Dán àwa iranṣẹ rẹ wò fún ọjọ́ mẹ́wàá, máa fún wa ní ẹ̀wà jẹ, kí o sì máa fún wa ní omi lásán mu.

Daniẹli 1

Daniẹli 1:11-15