Àwọn Ọba Kinni 9:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bi Solomoni pé, “Arakunrin mi, irú àwọn ìlú wo ni o fún mi yìí?” Ìdí nìyí tí wọ́n fi ń pe ilẹ̀ náà ní Kabulu títí di òní olónìí.

Àwọn Ọba Kinni 9

Àwọn Ọba Kinni 9:10-16