Àwọn Ọba Kinni 8:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni ọba ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli péjọ níwájú Àpótí Ẹ̀rí OLUWA, wọ́n sì fi ọpọlọpọ aguntan ati mààlúù tí ẹnikẹ́ni kò lè kà rúbọ.

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:1-6