Àwọn Ọba Kinni 8:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Lefi ati àwọn alufaa gbé Àpótí OLUWA wá, ati Àgọ́ OLUWA, ati àwọn ohun èlò mímọ́ tí ó wà ninu rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:1-11