Àwọn Ọba Kinni 7:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Iṣẹ́ ọnà ìtànná lílì ni wọ́n ṣe sára àwọn òpó náà.Bẹ́ẹ̀ ni iṣẹ́ ṣe parí lórí àwọn òpó náà.

Àwọn Ọba Kinni 7

Àwọn Ọba Kinni 7:15-26