Àwọn Ọba Kinni 7:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ri àwọn òpó mejeeji yìí sí àbáwọ Tẹmpili, wọ́n ri ọ̀kan sí ìhà gúsù, wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní Jakini; wọ́n ri ekeji sí apá àríwá, wọ́n sì pè é ní Boasi.

Àwọn Ọba Kinni 7

Àwọn Ọba Kinni 7:17-25