Àwọn Ọba Kinni 7:11-13 BIBELI MIMỌ (BM)

11. Òkúta olówó ńlá tí a wọ̀n kí á tó gé e, ati igi kedari, ni wọ́n fi ṣe ògiri rẹ̀.

12. Ìlè mẹta mẹta òkúta gbígbẹ́ tí a fi ìlé kan igi kedari là láàrin, ni wọ́n fi kọ́ àgbàlá ńlá náà yípo. Bẹ́ẹ̀ náà sì ni àgbàlá ti inú ilé OLUWA ati yàrá àbáwọlé.

13. Solomoni ọba ranṣẹ pé kí wọ́n lọ mú Huramu wá láti Tire,

Àwọn Ọba Kinni 7