Àwọn Ọba Kinni 6:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu oṣù Bulu, ní ọdún kọkanla ìjọba Solomoni ni wọ́n kọ́ ilé ìsìn náà parí patapata, ó sì rí bí wọ́n ti ṣètò pé kó rí gẹ́lẹ́. Ọdún meje ni ó gba Solomoni láti parí rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 6

Àwọn Ọba Kinni 6:31-38