Àwọn Ọba Kinni 6:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kọ́ ibi mímọ́ kan sí ọwọ́ ẹ̀yìn ilé ìsìn náà, inú ibi mímọ́ yìí ni wọ́n gbé Àpótí Ẹ̀rí OLUWA sí.

Àwọn Ọba Kinni 6

Àwọn Ọba Kinni 6:14-23