Àwọn Ọba Kinni 6:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbẹ́ àwòrán agbè ati òdòdó, wọ́n fi ṣe ọ̀ṣọ́ sára igi kedari tí wọ́n fi bo ògiri gbọ̀ngàn náà, òkúta tí wọ́n fi mọ ògiri ilé náà kò sì hàn síta rárá.

Àwọn Ọba Kinni 6

Àwọn Ọba Kinni 6:9-27