Àwọn Ọba Kinni 6:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kọ́ yàrá kan tí wọn ń pè ní Ibi-Mímọ́-Jùlọ, sí ọwọ́ ẹ̀yìn ilé ìsìn náà. Gígùn rẹ̀ jẹ́ ogún igbọnwọ, pákó kedari ni wọn fi gé e láti òkè dé ilẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 6

Àwọn Ọba Kinni 6:10-18