Àwọn Ọba Kinni 6:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Pákó igi kedari ni ó fi bo ara ògiri ilé náà ninu, láti òkè dé ilẹ̀. Pákó igi sipirẹsi ni wọ́n sì fi tẹ́ gbogbo ilẹ̀ rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 6

Àwọn Ọba Kinni 6:12-19