Àwọn Ọba Kinni 5:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ranṣẹ pada sí Solomoni, ó ní, “Mo gbọ́ iṣẹ́ tí o rán sí mi, n óo sì ṣe ohun tí o ní kí n ṣe fún ọ nípa igi kedari ati igi sipirẹsi.

Àwọn Ọba Kinni 5

Àwọn Ọba Kinni 5:7-11