Àwọn Ọba Kinni 5:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú ọba Hiramu dùn pupọ nígbà tí wọ́n jíṣẹ́ Solomoni fún un. Ó ní, “Ẹni ìyìn ni OLUWA lónìí, nítorí pé ó fún Dafidi ní ọlọ́gbọ́n ọmọ, láti jọba lórí orílẹ̀-èdè ńlá yìí.”

Àwọn Ọba Kinni 5

Àwọn Ọba Kinni 5:1-17