Àwọn Ọba Kinni 5:12 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA fún Solomoni ní ọgbọ́n gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ̀, alaafia sì wà láàrin òun ati Hiramu, àwọn mejeeji sì bá ara wọn dá majẹmu.

Àwọn Ọba Kinni 5

Àwọn Ọba Kinni 5:3-14