Àwọn Ọba Kinni 5:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdọọdún, Solomoni a máa fún Hiramu ní ọ̀kẹ́ kan (20,000) òṣùnwọ̀n kori ọkà, ati ọ̀kẹ́ kan (20,000) òṣùnwọ̀n kori òróró dáradára fún ìtọ́jú oúnjẹ fún Hiramu ati àwọn eniyan rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 5

Àwọn Ọba Kinni 5:5-18