Àwọn Ọba Kinni 4:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Solomoni jọba gbogbo ilẹ̀ Israẹli,

2. Orúkọ àwọn olórí ninu àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ nìwọ̀nyí: Asaraya, ọmọ Sadoku ni alufaa.

3. Elihorefi ati Ahija, meji ninu àwọn ọmọ Ṣiṣa ni akọ̀wé ní ààfin ọba. Jehoṣafati, ọmọ Ahiludi ni olùtọ́jú àwọn ìwé àkọsílẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 4