Àwọn Ọba Kinni 5:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Hiramu, ọba Tire, gbọ́ pé Solomoni ni ó gun orí oyè lẹ́yìn baba rẹ̀, ó rán oníṣẹ́ sí i; nítorí ọ̀rẹ́ ni òun ati Dafidi, wọ́n sì fẹ́ràn ara wọn.

Àwọn Ọba Kinni 5

Àwọn Ọba Kinni 5:1-11