Àwọn Ọba Kinni 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA fara han Solomoni ní ojú àlá ní òru ọjọ́ kan ní Gibeoni, ó sì bi í pé, “Kí ni o fẹ́ kí n fún ọ?”

Àwọn Ọba Kinni 3

Àwọn Ọba Kinni 3:1-10