Àwọn Ọba Kinni 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba a máa lọ sí Gibeoni láti rúbọ, nítorí pé níbẹ̀ ni pẹpẹ tí ó lókìkí jùlọ nígbà náà wà. A máa fi ẹgbẹrun (1,000) ẹran rú ẹbọ sísun lórí pẹpẹ náà.

Àwọn Ọba Kinni 3

Àwọn Ọba Kinni 3:1-14