Àwọn Ọba Kinni 3:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo jí ní ọjọ́ keji láti fún ọmọ ní oúnjẹ, mo rí i pé ó ti kú. Ṣugbọn nígbà tí mo yẹ̀ ẹ́ wò fínnífínní, mo rí i pé kì í ṣe ọmọ tèmi ni.”

Àwọn Ọba Kinni 3

Àwọn Ọba Kinni 3:12-23