Àwọn Ọba Kinni 3:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá dìde ní ọ̀gànjọ́ òru, ó wá jí ọmọ tèmi gbé ní ẹ̀gbẹ́ mi nígbà tí mo sùn lọ, ó tẹ́ ẹ sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀, ó sì tẹ́ òkú ọmọ tirẹ̀ sọ́dọ̀ mi.

Àwọn Ọba Kinni 3

Àwọn Ọba Kinni 3:17-28