Àwọn Ọba Kinni 22:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ ọdún marundinlogoji ni Jehoṣafati nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mẹẹdọgbọn. Asuba ọmọ Ṣilihi ni ìyá rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:38-45