Àwọn Ọba Kinni 22:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹrin tí Ahabu, ọba Israẹli, gun orí oyè, ni Jehoṣafati, ọmọ Asa, gun orí oyè ní ilẹ̀ Juda.

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:40-50