Àwọn Ọba Kinni 2:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn OLUWA yóo bukun mi, yóo sì fi ẹsẹ̀ ìjọba Dafidi múlẹ̀ títí lae.

Àwọn Ọba Kinni 2

Àwọn Ọba Kinni 2:39-46