Àwọn Ọba Kinni 19:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dé ibi ihò àpáta kan, ó sì sùn níbẹ̀ mọ́jú ọjọ́ keji.OLUWA bá a sọ̀rọ̀, ó bi í pé, “Elija, kí ni ò ń ṣe níhìn-ín?”

Àwọn Ọba Kinni 19

Àwọn Ọba Kinni 19:8-16