Àwọn Ọba Kinni 19:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Elija dìde, ó jẹun, ó sì tún mu omi. Oúnjẹ náà sì fún un ní agbára láti rìn fún ogoji ọjọ́ tọ̀sán-tòru títí tí ó fi dé orí òkè Horebu, òkè Ọlọrun.

Àwọn Ọba Kinni 19

Àwọn Ọba Kinni 19:5-14