Àwọn Ọba Kinni 19:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wò yíká, ó sì rí ìṣù àkàrà kan, ati ìkòkò omi kan lẹ́bàá ìgbèrí rẹ̀. Ó jẹun, ó mu omi, ó sì tún dùbúlẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 19

Àwọn Ọba Kinni 19:3-16