Àwọn Ọba Kinni 19:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dùbúlẹ̀ lábẹ́ igi náà, ó sì sùn. Lójijì, angẹli kan fi ọwọ́ kàn án, ó sì wí fún un pé, “Dìde kí o jẹun.”

Àwọn Ọba Kinni 19

Àwọn Ọba Kinni 19:1-9