Àwọn Ọba Kinni 18:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn eniyan náà rí i, wọ́n dojúbolẹ̀, wọ́n wí pé, “OLUWA ni Ọlọrun! OLUWA ni Ọlọrun!”

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:35-46