Àwọn Ọba Kinni 18:38 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá sọ iná sílẹ̀, iná náà sì jó ẹbọ náà ati igi, ati òkúta. Ó jó gbogbo ilẹ̀ ibẹ̀, ó sì lá gbogbo omi tí ó wà ninu kòtò.

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:34-46