Àwọn Ọba Kinni 17:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu odò yìí ni o óo ti máa bu omi mu, mo sì ti pàṣẹ fún àwọn ẹyẹ ìwò kan pé kí wọ́n máa gbé oúnjẹ wá fún ọ níbẹ̀.”

Àwọn Ọba Kinni 17

Àwọn Ọba Kinni 17:1-11