Àwọn Ọba Kinni 17:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kúrò níhìn-ín, kí o doríkọ apá ìhà ìlà oòrùn, kí o sì fi ara pamọ́ lẹ́bàá odò Keriti, tí ó wà ní apá ìhà ìlà oòrùn odò Jọdani.

Àwọn Ọba Kinni 17

Àwọn Ọba Kinni 17:2-5