Àwọn Ọba Kinni 16:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ọ̀nà burúkú tí Jeroboamu ọmọ Nebati rìn ni òun náà ń tọ̀. Òun náà jẹ́ kí Israẹli dẹ́ṣẹ̀, ó sì mú OLUWA Ọlọrun Israẹli bínú nítorí oriṣa tí wọn ń bọ.

Àwọn Ọba Kinni 16

Àwọn Ọba Kinni 16:24-27