Àwọn Ọba Kinni 16:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nǹkan tí Omiri ṣe burú lójú OLUWA, ibi tí ó ṣe pọ̀ ju ti gbogbo àwọn tí wọ́n wà ṣáájú rẹ̀ lọ.

Àwọn Ọba Kinni 16

Àwọn Ọba Kinni 16:15-29