Àwọn Ọba Kinni 16:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Níkẹyìn, àwọn tí wọ́n wà lẹ́yìn Omiri ṣẹgun àwọn tí wọ́n wà lẹ́yìn Tibini, ọmọ Ginati. Tibini kú, Omiri sì jọba.

Àwọn Ọba Kinni 16

Àwọn Ọba Kinni 16:16-27