Àwọn Ọba Kinni 16:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ikú Simiri àwọn ọmọ Israẹli pín sí ọ̀nà meji. Àwọn kan wà lẹ́yìn Tibini, ọmọ Ginati, pé òun ni kí ó jọba. Àwọn yòókù sì wà lẹ́yìn Omiri.

Àwọn Ọba Kinni 16

Àwọn Ọba Kinni 16:12-26