Àwọn Ọba Kinni 16:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Simiri ti gorí oyè, tí ó bẹ̀rẹ̀ sí jọba ni ó pa gbogbo àwọn ìdílé Baaṣa patapata. Gbogbo àwọn ìbátan ati ọ̀rẹ́ rẹ̀ lọkunrin ni ó pa láìdá ẹnikẹ́ni sí.

Àwọn Ọba Kinni 16

Àwọn Ọba Kinni 16:2-14