Àwọn Ọba Kinni 16:10 BIBELI MIMỌ (BM)

ní ọdún kẹtadinlọgbọn tí Asa ọba Juda gorí oyè, Simiri bá wọlé, ó fi idà ṣá Ela pa, ó bá fi ara rẹ̀ jọba dípò Ela.

Àwọn Ọba Kinni 16

Àwọn Ọba Kinni 16:7-11