Àwọn Ọba Kinni 15:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹsibẹ, nítorí ti Dafidi, OLUWA Ọlọrun fún Abijamu ní ọmọkunrin kan tí ó gorí oyè lẹ́yìn rẹ̀, ní Jerusalẹmu, tí ó sì dáàbò bo Jerusalẹmu.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:1-9