Àwọn Ọba Kinni 15:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà gbogbo ni Asa ọba Juda, ati Baaṣa, ọba Israẹli ń gbógun ti ara wọn, ní gbogbo ìgbà tí wọ́n wà lórí oyè.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:7-22