Àwọn Ọba Kinni 13:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀ṣẹ̀ ni ohun tí ó ṣe yìí, ẹ̀ṣẹ̀ yìí ni ó sì run ìran rẹ̀ lórí oyè, tí wọ́n fi parun patapata lórílẹ̀ ayé.

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:31-34