Àwọn Ọba Kinni 13:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn gbogbo nǹkan wọnyi, Jeroboamu, ọba Israẹli kò yipada kúrò ninu ìwà burúkú rẹ̀. Ṣugbọn ó ń yan ẹnikẹ́ni tí ó bá wù ú láàrin àwọn eniyan ó sì ń fi wọ́n jẹ alufaa ní àwọn ibi pẹpẹ ìrúbọ káàkiri.

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:31-34